Ẹkọ òòkàdẹrí jẹ́ ẹkọ ẹrí ti a ri ninu àwọn agbo òòkà àti bí a ti le fa ìmọ yọ lórí ìbẹwò àwọn agbo òòkà yi.
Àròpín jẹ́ ìrò àwọn ọ̀wọ́ òòkà kan, tí a sì pín pẹ̀lú iye òòkà tó wà nínú ọ̀wọ́ yi.
Òòkà t’àárín jẹ́ òòkà tó wà láàrín àwọn ọ̀wọ́ òòkà kan. Ìlàjì àwọn òòkà láàrín ọ̀wọ́ òòkà yi kéré ju òòkà t’àárín. Ìlàjì wọn sì pọ ju ú.
Òòkà àpọjù ni iye tó pọ jù tàbí yá jù.
Ìgbọn jẹ́ ìyàtọ láàrín iye tó kéré jù ati tó tóbi jù láàrín ọ̀wọ́ òòkà kan, Ẹ fi sí ìrántí pé ìgbọn jẹ́ ẹyọ òòkà kan, kìí ṣe ọpọ òòkà.
English Translation...
Statistics is the study of sets of data and the ability to draw conclusions based on an examination of the data.
Statistics is the study of sets of data and the ability to draw conclusions based on an examination of the data.
Mean or the Arithmetic mean is the sum of a list of numbers, divided by the total number of numbers in the list.
Median (median value) is the ‘middle value’ of a list. The number such that at half the numbers in the list are smaller than it. And half are bigger than it.
Mode is the most common (frequent) value. A list can have more than one mode.
Range is the difference between the largest and the smallest value in a list. Note that the range is a single number, not many numbers.
Ìtumọ̀ (Translation)
STATISTICS = ÒÒKÀDẸRI (òòkà di ẹri: numbers become evidence)
PROBABILITY = ÌWỌN-ÌṢEÉṢE (measurement of possibility)
MEAN (AVERAGE) = ÀRÒPÍN
MEDIAN = ÀÁRÍN
MEDIAN VALUE = IYE T’ÀÁRÍN
MODE = IYE ÀPỌJÙ
THE LAW OF AVERAGES = ÀWỌN ÒFI ÀRÒPÍN
RANGE = ÌGBỌN
DATA = Ẹ̀RÍ
SET OF NUMBERS = AGBO ÒÒKÀ
STATISTICS = ÒÒKÀDẸRI (òòkà di ẹri: numbers become evidence)
PROBABILITY = ÌWỌN-ÌṢEÉṢE (measurement of possibility)
MEAN (AVERAGE) = ÀRÒPÍN
MEDIAN = ÀÁRÍN
MEDIAN VALUE = IYE T’ÀÁRÍN
MODE = IYE ÀPỌJÙ
THE LAW OF AVERAGES = ÀWỌN ÒFI ÀRÒPÍN
RANGE = ÌGBỌN
DATA = Ẹ̀RÍ
SET OF NUMBERS = AGBO ÒÒKÀ
No comments:
Post a Comment