Tuesday 14 February 2017

Ọ̀̀rọ̀ àwọn àgbà - Voice of the elders...

Eji Ogbe says… it matters how you present yourself...
Ìṣẹ́ ko ti ibi kan mu'ni
Ìyà ko ti ibi kan jẹ eniyan
Bi o ba rin ìrìn oṣi
Bi o ba ojú ìṣẹ́ wọ̀lú
Igbákígbá ni wọn a fi bu omi fun ni

In English….
Penury does not lay hold of just one part of the body
Hardship does not attack just one part of the body
If you go about like a beggar
If you enter town with look of destitution
You will be offered water in any old calabash

Eji Ogbe says… look after your own...
Akọ ajá lọ́lá
Ago aala ni iyi oṣupa
Ọmọ bi ilẹkẹ, ọmọ bi idẹ
Ọmọ ẹni lọmọ ẹni
Ọmo ẹni ko le ṣe idi bẹ̀bẹ̀rẹ̀ bẹbẹrẹ ka so ìlẹ̀kẹ̀ mọ idi ọmọ ẹloomi

In English…..
Honour is given to a male dog
Venus is the glory of the new moon
A child is like beads, a child is like brass
One's own child will always be one's own
If one's child has a crooked waist, one does not because of that tie beads on the waist of another person's child.

No comments:

Post a Comment