Thursday 27 April 2017

Epistle of Eji Ogbe - Ọ̀tọ́wútọ́wútọ́wú

Epistle of Eji Ogbe...
Ọ̀tọ́wútọ́wútọ́wú,
Ọ̀rọ́wúrọ́wúrọ́wú,
Ọ̀tọ̀tọ̀ la jẹpà;
Ọ̀tọ̀tọ̀ lajẹ imúmú;
Lọ́tọ̀lọ́tọ̀ ni wọn sọ olu etutu sẹnu
Bi erun ja, bi erun tá,
Wọn a fi iru ba ara wọn tèlétèlétèlé
Da fun Kugbagbe ti ṣe ọmọ agba Ọṣa Wuji.
O ni Iku wa gbagbe mi loni.
Agbẹ rokoroko wọn kaṣai gbagbe ewe kan sebe
Arun gbagbe mi loni.
Agbẹ rokoroko wọn kaṣai gbagbe ewe kan sebe
Eji Ogbe ni.
Ọ̀tọ́wútọ́wútọ́wú,
Ọ̀rọ́wúrọ́wúrọ́wú,
One by one we eat peanuts;
One by one we eat tiger nuts;
One by one we throw queen ants into the mouth.
When driver ants fight, when driver ants sting,
They touch each other lightly with their tails
Cast for "Death forgets" who was the child of old Oriṣa Wuji.
He said Death, forget me today.
Sickness, forget me today.
Farmers hoe and hoe, they forget not one weed on the yam heaps.
This is Eji Ogbe.

No comments:

Post a Comment