Thursday, 27 April 2017

Orí re ní dádé owó

Èjì Ogbe says…
Orí re ní dádé owó;
Ọrùn ire ní ṣẹ̀gìdá ìlẹ̀kẹ̀;
Ìdí rere ní fí ẹní ore ṣìtẹ́ 
Ló da fún Ara tùmí tí ṣe obìnrin Òòṣà
Òòṣà laa lórí.
Ó ní Òòṣà tí mo bá tẹtẹ ìrẹ ni ilari ìwọ Òrìṣà ní mo da.
Àrẹ òkè ki tẹ́ lójú ẹni la lórí.
Èjì Ogbè ní jẹ́ bẹẹ.
A lucky head wears a crown of cowries;
A lucky neck wears jasper beads;
Lucky hips use an expensive mat as a throne
Was the one who cast for “My body is at ease” who was the wife of Òrìṣà.
Òrìṣà initiated her.
She said, “Òrìṣà, if I use your throne, I am unfaithful to you, Òrìṣà”.
The first born of the hill is not disgraced in the eyes of his initiator.
Èjì Ogbe is like this.

No comments:

Post a Comment